Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Esek 42:11 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ati ọ̀na iwaju wọn ti gẹgẹ bi iri awọn yará ti o wà li ọ̀na ariwa, bi nwọn ti gùn mọ, bẹ̃ ni nwọn gbòro mọ: ati gbogbo ijade wọn si dabi iṣe wọn, ati bi ilẹkùn wọn.

Ka pipe ipin Esek 42

Wo Esek 42:11 ni o tọ