Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Esek 40:39 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ati ni iloro ẹnu-ọ̀na na tabili meji mbẹ nihà ìhin, ati tabili meji nihà ọ̀hun, lati ma pa ẹran ẹbọ sisun, ati ọrẹ ẹbọ ẹ̀ṣẹ, ati ọrẹ ẹbọ irekọja lori wọn.

Ka pipe ipin Esek 40

Wo Esek 40:39 ni o tọ