Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Esek 40:3 Yorùbá Bibeli (YCE)

O si mu mi wá sibẹ, si kiyesi i, ọkunrin kan mbẹ, ẹniti irí rẹ̀ dabi irí bàba, pẹlu okùn ọ̀gbọ li ọwọ́ rẹ̀, ati ije iwọ̀nlẹ; on si duro ni ẹnu-ọ̀na.

Ka pipe ipin Esek 40

Wo Esek 40:3 ni o tọ