Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Esek 40:29 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ati awọn yará kékèké rẹ̀, ati atẹrigbà rẹ̀, ati iloro rẹ̀, gẹgẹ bi ìwọn wọnyi: ferese pupọ̀ si mbẹ nibẹ ati ni iloro rẹ̀ yika: o jẹ ãdọta igbọnwọ ni gigùn, igbọnwọ mẹ̃dọgbọn ni ibú.

Ka pipe ipin Esek 40

Wo Esek 40:29 ni o tọ