Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Esek 4:4 Yorùbá Bibeli (YCE)

Fi iha osì rẹ dubulẹ, ki o si fi ẹ̀ṣẹ ile Israeli sori rẹ̀: gẹgẹ bi iye ọjọ ti iwọ o dubulẹ sori rẹ̀ ni iwọ o ru ẹ̀ṣẹ wọn.

Ka pipe ipin Esek 4

Wo Esek 4:4 ni o tọ