Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Esek 4:2 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ki o si dótì i, ki o si mọ ile iṣọ tì i, ki o si mọ odi tì i, ki o si gbe ogun si i, ki o si to õlù yi i ka.

Ka pipe ipin Esek 4

Wo Esek 4:2 ni o tọ