Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Esek 4:16 Yorùbá Bibeli (YCE)

O si wi fun mi pe, Ọmọ enia, kiye si i, emi o ṣẹ ọpá onjẹ ni Jerusalemu: nwọn o si jẹ akara nipa ìwọn, ati pẹlu itọju; nwọn o si mu omi nipa ìwọn ati pẹlu iyanu.

Ka pipe ipin Esek 4

Wo Esek 4:16 ni o tọ