Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Esek 38:4 Yorùbá Bibeli (YCE)

Emi o si dá ọ padà, emi o si fi ìwọ kọ́ ọ li ẹ̀rẹkẹ́, emi o si mu ọ jade wá, ati gbogbo ogun rẹ, ẹṣin ati ẹlẹṣin, gbogbo wọn li a wọ̀ laṣọ daradara, ani ẹgbẹ́ nla pẹlu apata on asà, gbogbo wọn dì idà mu:

Ka pipe ipin Esek 38

Wo Esek 38:4 ni o tọ