Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Esek 38:22 Yorùbá Bibeli (YCE)

Emi o si fi ajàkalẹ arùn ati ẹjẹ ba a wijọ; emi o si rọ̀ ojò pupọ̀, ati yìnyin nla, iná ati imi-ọjọ, si i lori, ati sori áwọn ẹgbẹ rẹ̀, ati sori ọ̀pọlọpọ enia ti o wà pẹlu rẹ̀.

Ka pipe ipin Esek 38

Wo Esek 38:22 ni o tọ