Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Esek 38:20 Yorùbá Bibeli (YCE)

Awọn ẹja inu okun, ati awọn ẹiyẹ oju ọrun, ati awọn ẹranko inu igbó, ati ohun gbogbo ti nrakò lori ilẹ, ati gbogbo enia ti mbẹ loju ilẹ, yio si mì niwaju mi, a o si bì òke-nla ṣubu, ati gbogbo ibi giga yio ṣubu, olukuluku ogiri yio ṣubu lulẹ.

Ka pipe ipin Esek 38

Wo Esek 38:20 ni o tọ