Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Esek 38:17 Yorùbá Bibeli (YCE)

Bayi li Oluwa Ọlọrun wi; Iwọ li ẹniti mo ti sọ̀rọ rẹ̀ nigba atijọ lati ọwọ́ awọn iranṣẹ mi awọn woli Israeli, ti nwọn sọtẹlẹ li ọjọ wọnni li ọdun pupọ pe, emi o mu ọ wá dojukọ wọn?

Ka pipe ipin Esek 38

Wo Esek 38:17 ni o tọ