Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Esek 38:13 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ṣeba, ati Dedani, ati awọn oniṣòwo Tarṣiṣi, pẹlu gbogbo awọn ọmọ kiniun wọn, yio si wi fun ọ pe, Ikogun ni iwọ wá kó? lati wá mu ohun ọdẹ li o ṣe gbá awọn ẹgbẹ́ rẹ jọ? lati wá rù fadaka ati wura lọ, lati wá rù ohun-ọsìn ati ẹrù, lati wá kó ikogun nla?

Ka pipe ipin Esek 38

Wo Esek 38:13 ni o tọ