Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Esek 37:7 Yorùbá Bibeli (YCE)

Bẹ̃ni mo ṣotẹlẹ gẹgẹ bi a ti paṣẹ fun mi: bi mo si ti sọtẹlẹ, ariwo ta, si wò o, mimì kan wà, awọn egungun na si wá ọdọ ara wọn, egungun si egungun rẹ̀.

Ka pipe ipin Esek 37

Wo Esek 37:7 ni o tọ