Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Esek 37:25 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nwọn o si ma gbe ilẹ ti emi ti fi fun Jakobu iranṣẹ mi, nibiti awọn baba nyin ti gbe; nwọn o si ma gbe inu rẹ̀, awọn, ati awọn ọmọ wọn, ati awọn ọmọ ọmọ wọn lailai: Dafidi iranṣẹ mi yio si ma jẹ ọmọ-alade wọn lailai.

Ka pipe ipin Esek 37

Wo Esek 37:25 ni o tọ