Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Esek 37:22 Yorùbá Bibeli (YCE)

Emi o si sọ wọn di orilẹ-ède kan ni ilẹ lori oke-nla Israeli; ọba kan ni yio si jẹ lori gbogbo wọn: nwọn kì yio si jẹ orilẹ-ède meji mọ, bẹ̃ni a kì yio sọ wọn di ijọba meji mọ rara.

Ka pipe ipin Esek 37

Wo Esek 37:22 ni o tọ