Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Esek 37:14 Yorùbá Bibeli (YCE)

Emi o si fi ẹmi mi sinu nyin, ẹnyin o si yè, emi o si mu nyin joko ni ilẹ ti nyin: nigbana li ẹnyin o mọ̀ pe, emi Oluwa li o ti sọ ọ, ti o si ti ṣe e, li Oluwa wi.

Ka pipe ipin Esek 37

Wo Esek 37:14 ni o tọ