Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Esek 36:8 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ṣugbọn ẹnyin, oke Israeli, ẹnyin o yọ ẹka jade, ẹ o si so eso nyin fun Israeli enia mi; nitori nwọn fẹrẹ̀ de.

Ka pipe ipin Esek 36

Wo Esek 36:8 ni o tọ