Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Esek 36:5 Yorùbá Bibeli (YCE)

Bayi li Oluwa Ọlọrun wi; Nitõtọ ninu iná owu mi li emi ti sọ̀rọ si awọn keferi iyokù, ati si gbogbo Idumea, ti o ti fi ayọ̀ inu wọn gbogbo yàn ilẹ mi ni iní wọn, pẹlu àrankan inu, lati ta a nù fun ijẹ.

Ka pipe ipin Esek 36

Wo Esek 36:5 ni o tọ