Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Esek 36:38 Yorùbá Bibeli (YCE)

Gẹgẹ bi ọwọ́-ẹran mimọ́, bi ọwọ́-ẹran Jerusalemu ni àse wọn ti o ni ironu, bẹ̃ni ilu ti o di ahoro yio kún fun enia: nwọn o si mọ̀ pe, emi li Oluwa.

Ka pipe ipin Esek 36

Wo Esek 36:38 ni o tọ