Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Esek 36:3 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nitorina sọtẹlẹ, ki o si wipe, Bayi li Oluwa Ọlọrun wi, pe, Nitõtọ nitori nwọn ti sọ ọ di ahoro, ti nwọn si gbe ọ mì niha gbogbo, ki ẹnyin ba le jẹ ini fun awọn keferi iyokù, ti a mu nyin si ẹnu, ti ẹnyin si jasi ẹ̀gan awọn enia:

Ka pipe ipin Esek 36

Wo Esek 36:3 ni o tọ