Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Esek 36:20 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nigbati awọn si wọ̀ inu awọn keferi, nibiti nwọn lọ, nwọn bà orukọ mimọ́ mi jẹ, nigbati nwọn wi fun wọn pe, Awọn wọnyi li enia Oluwa, nwọn si ti jade kuro ni ilẹ rẹ̀.

Ka pipe ipin Esek 36

Wo Esek 36:20 ni o tọ