Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Esek 36:11 Yorùbá Bibeli (YCE)

Emi o si mu enia ati ẹranko bi si i lori nyin; nwọn o si pọ̀ si i, nwọn o si rẹ̀: emi o si mu nyin joko ni ibugbe nyin, bi ti atijọ, emi o si ṣe si nyin jù igbà ibẹ̀rẹ nyin lọ: ẹnyin o si mọ̀ pe, emi li Oluwa.

Ka pipe ipin Esek 36

Wo Esek 36:11 ni o tọ