Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Esek 34:4 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ẹnyin kò mu alailera lara le, bẹ̃ni ẹ kò mu eyiti kò sàn li ara da, bẹ̃ni ẹ kò dì eyiti a ṣá lọ́gbẹ, bẹ̃ni ẹ kò tun mu eyi ti a ti lé lọ padà bọ̀, bẹ̃ni ẹ kò wá eyiti o sọnu, ṣugbọn ipá ati ìka li ẹ ti fi nṣe akoso wọn.

Ka pipe ipin Esek 34

Wo Esek 34:4 ni o tọ