Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Esek 34:27 Yorùbá Bibeli (YCE)

Igi igbẹ́ yio si so eso rẹ̀, ilẹ yio si ma mu asunkun rẹ̀ wá, nwọn o si wà li alafia ni ilẹ wọn, nwọn o si mọ̀ pe emi li Oluwa, nigbati emi o ti ṣẹ́ èdídi àjaga wọn, ti emi o si ti gbà wọn lọwọ awọn ti nwọn nsìn bi ẹrú.

Ka pipe ipin Esek 34

Wo Esek 34:27 ni o tọ