Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Esek 34:2 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ọmọ enia, sọtẹlẹ si awọn oluṣọ́ agutan Israeli, sọtẹlẹ, ki o si wi fun wọn pe, Bayi li Oluwa Ọlọrun wi fun awọn oluṣọ́ agutan; pe, Egbé ni fun awọn oluṣọ́ agutan Israeli, ti mbọ́ ara wọn, awọn oluṣọ́ agutan kì ba bọ́ ọwọ́-ẹran?

Ka pipe ipin Esek 34

Wo Esek 34:2 ni o tọ