Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Esek 34:13 Yorùbá Bibeli (YCE)

Emi o si mu wọn jade kuro ninu awọn orilẹ-ède, emi o si kó wọn jọ lati ilẹ gbogbo, emi o si mu wọn wá si ilẹ ara wọn, emi o si bọ́ wọn lori oke Israeli, lẹba odò, ati ni ibi gbigbé ni ilẹ na.

Ka pipe ipin Esek 34

Wo Esek 34:13 ni o tọ