Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Esek 33:6 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ṣugbọn bi oluṣọ́ na bá ri ti idà mbọ̀, ti kò si fun ipè, ti a kò si kìlọ fun awọn enia; bi idà ba de, ti o ba si mu ẹnikẹni lãrin wọn, a mu u kuro nitori aiṣedẽde rẹ̀, ṣugbọn ẹjẹ rẹ̀ li emi o bere lọwọ oluṣọ́ na.

Ka pipe ipin Esek 33

Wo Esek 33:6 ni o tọ