Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Esek 33:27 Yorùbá Bibeli (YCE)

Iwọ wi bayi fun wọn pe, Bayi li Oluwa Ọlọrun wi; Bi emi ti wà, nitõtọ, awọn ti o wà ninu ahoro na yio ti ipa idà ṣubu, ẹniti o si wà ni gbangba oko li emi o si fi fun ẹranko lati pajẹ, awọn ti o si wà ninu odi ati ninu ihò okuta yio ti ipa ajakalẹ-àrun kú.

Ka pipe ipin Esek 33

Wo Esek 33:27 ni o tọ