Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Esek 33:22 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ọwọ́ Oluwa si wà lara mi li àṣalẹ, ki ẹniti o salà na to de; o si ti ṣi ẹnu mi, titi on fi wá sọdọ mi li owurọ; ẹnu mi si ṣi, emi kò si yadi mọ.

Ka pipe ipin Esek 33

Wo Esek 33:22 ni o tọ