Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Esek 33:11 Yorùbá Bibeli (YCE)

Sọ fun wọn pe, Bi emi ti wà, ni Oluwa Ọlọrun wi, emi kò ni inu-didun ni ikú enia buburu, ṣugbọn ki enia buburu yipada kuro ninu ọ̀na rẹ̀ ki o si yè: ẹ yipada, ẹ yipada kuro ninu ọ̀na buburu nyin; nitori kini ẹnyin o ṣe kú, Ile Israeli?

Ka pipe ipin Esek 33

Wo Esek 33:11 ni o tọ