Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Esek 32:26 Yorùbá Bibeli (YCE)

Meṣeki ati Tubali wà nibẹ, ati gbogbo ọ̀pọlọpọ enia rẹ̀: awọn ibojì rẹ̀ yi i ka: gbogbo wọn alaikọlà ti a fi idà pa, bi nwọn tilẹ dá ẹ̀ru wọn silẹ ni ilẹ alãye.

Ka pipe ipin Esek 32

Wo Esek 32:26 ni o tọ