Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Esek 32:2 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ọmọ enia, pohunrére fun Farao ọba Egipti, si wi fun u pe, Iwọ dabi ẹgbọ̀rọ kiniun awọn orilẹ-ède, iwọ si dabi dragoni ninu okun, iwọ si jade wá pẹlu awọn odò rẹ, iwọ ti fi ẹsẹ rẹ rú omi, o si ti bà awọn odò wọn jẹ́.

Ka pipe ipin Esek 32

Wo Esek 32:2 ni o tọ