Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Esek 32:10 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nitõtọ, emi o mu ki ẹnu yà ọ̀pọlọpọ orilẹ-ède si ọ, awọn ọba wọn yio si bẹ̀ru gidigidi nitori rẹ, nigbati emi o ba mì idà mi niwaju wọn; nwọn o si warìri nigbagbogbo, olukuluku enia fun ẹmi ara rẹ̀, li ọjọ iṣubu rẹ.

Ka pipe ipin Esek 32

Wo Esek 32:10 ni o tọ