Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Esek 30:6 Yorùbá Bibeli (YCE)

Bayi li Oluwa wi; Awọn pẹlu ti nwọn gbe Egipti ró yio ṣubu; ati igberaga agbara rẹ̀ yio sọkalẹ: lati Migdoli lọ de Siene ni nwọn o ti ipà idà ṣubu ninu rẹ̀, li Oluwa Ọlọrun wi.

Ka pipe ipin Esek 30

Wo Esek 30:6 ni o tọ