Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Esek 30:13 Yorùbá Bibeli (YCE)

Bayi li Oluwa Ọlọrun wi; emi o pa awọn oriṣa run pẹlu, emi o si jẹ ki ere wọn tán ni Nofi; kì yio si si ọmọ alade kan ni ilẹ Egipti mọ́: emi o si fi ẹ̀ru si ilẹ Egipti.

Ka pipe ipin Esek 30

Wo Esek 30:13 ni o tọ