Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Esek 27:24 Yorùbá Bibeli (YCE)

Wọnyi li awọn oniṣòwo rẹ li onirũru nkan, ni aṣọ alaro, ati oniṣẹ-ọnà, ati apoti aṣọ oniyebiye, ti a fi okùn dì, ti a si fi igi kedari ṣe, ninu awọn oniṣòwo rẹ.

Ka pipe ipin Esek 27

Wo Esek 27:24 ni o tọ