Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Esek 27:21 Yorùbá Bibeli (YCE)

Arabia, ati gbogbo awọn ọmọ-alade Kedari, awọn ni awọn oniṣòwo rẹ, ni ọdọ-agutan, ati agbò, ati ewurẹ; ninu wọnyi ni nwọn ṣe oniṣòwo rẹ.

Ka pipe ipin Esek 27

Wo Esek 27:21 ni o tọ