Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Esek 26:15 Yorùbá Bibeli (YCE)

Bayi li Oluwa Ọlọrun wi si Tire; awọn erekùṣu kì yio ha mì-titi nipa iró iṣubu rẹ, nigbati awọn ti o gbọgbẹ́ kigbe, nigbati a ṣe ipani li ãrin rẹ?

Ka pipe ipin Esek 26

Wo Esek 26:15 ni o tọ