Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Esek 26:10 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nitori ọ̀pọ awọn ẹṣin rẹ̀ ẽkuru wọn yio bò ọ: odi rẹ yio mì nipa ariwo awọn ẹlẹṣin, ati kẹkẹ́, ati kẹkẹ́ ogun, nigbati yio wọ̀ inu odi rẹ lọ, gẹgẹ bi enia ti wọ̀ inu ilu ti a fọ́.

Ka pipe ipin Esek 26

Wo Esek 26:10 ni o tọ