Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Esek 24:25 Yorùbá Bibeli (YCE)

Pẹlupẹlu, iwọ ọmọ enia, kì yio ha ṣe pe, ni ijọ na nigbati mo ba gbà agbara wọn, ayọ̀ ogo wọn, ifẹ oju wọn, ati eyiti nwọn gbe ọkàn wọn le, ọmọ wọn ọkunrin, ati ọmọ wọn obinrin, kuro lọdọ wọn,

Ka pipe ipin Esek 24

Wo Esek 24:25 ni o tọ