Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Esek 24:21 Yorùbá Bibeli (YCE)

Sọ fun ile Israeli pe, Bayi li Oluwa Ọlọrun wi, kiyesi i emi o sọ ibi mimọ́ mi di aimọ́, titayọ agbara nyin, ifẹ oju nyin, ikãnu ọkàn nyin, ati ọmọ nyin ọkunrin ati ọmọ nyin obinrin, ti ẹnyin ti fi silẹ, yio ti ipa idà ṣubu.

Ka pipe ipin Esek 24

Wo Esek 24:21 ni o tọ