Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Esek 22:28 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ati awọn wolĩ rẹ̀ ti fi ẹfun kùn wọn, nwọn nri asan, nwọn si nfọ afọ̀ṣẹ eke si wọn, wipe, Bayi li Oluwa Ọlọrun wi, nigbati o ṣepe Oluwa kò sọ̀rọ.

Ka pipe ipin Esek 22

Wo Esek 22:28 ni o tọ