Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Esek 22:20 Yorùbá Bibeli (YCE)

Gẹgẹ bi nwọn ti ima ko fadaka, ati idẹ, ati irin, ati ojé, ati tánganran jọ si ãrin ileru, lati fin iná si i, ki a lè yọ́ ọ, bẹ̃ni emi o kó nyin ni ibinu mi, ati irúnu mi, emi o si fi nyin sibẹ emi o yọ́ nyin.

Ka pipe ipin Esek 22

Wo Esek 22:20 ni o tọ