Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Esek 20:44 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ẹnyin o si mọ̀ pe emi ni Oluwa, nigbati emi ti ṣiṣẹ pẹlu nyin nitori orukọ mi, ki iṣe gẹgẹ bi ọ̀na buburu nyin, tabi gẹgẹ bi iṣe bibajẹ nyin, ẹnyin ile Israeli, ni Oluwa Ọlọrun wi.

Ka pipe ipin Esek 20

Wo Esek 20:44 ni o tọ