Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Esek 20:31 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nitori nigbati ẹnyin nta ọrẹ nyin, nigbati ẹnyin mu ọmọ nyin kọja lãrin iná, ẹnyin fi oriṣa nyin bà ara nyin jẹ́, ani titi o fi di oni oloni: ẹnyin o ha si bere lọwọ mi, Iwọ ile Israeli? Bi mo ti wà, ni Oluwa Ọlọrun wi, lọwọ mi kọ́ ẹnyin o bere.

Ka pipe ipin Esek 20

Wo Esek 20:31 ni o tọ