Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Esek 18:6 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ti kò si jẹun lori oke, ti kò si gbe oju rẹ̀ soke si awọn oriṣa ile Israeli, ti kò si bà obinrin aladugbo rẹ̀ jẹ, ti kò sì sunmọ obinrin ti o wà ninu aimọ́ rẹ̀.

Ka pipe ipin Esek 18

Wo Esek 18:6 ni o tọ