Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Esek 18:30 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nitorina emi o dá nyin lẹjọ, ile Israeli, olukuluku gẹgẹ bi ọ̀na rẹ̀, ni Oluwa Ọlọrun wi. Ẹ yipada, ki ẹ si yi kuro ninu gbogbo irekọja nyin; bẹ̃ni aiṣedẽde kì yio jẹ iparun nyin.

Ka pipe ipin Esek 18

Wo Esek 18:30 ni o tọ