Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Esek 18:20 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ọkàn ti o ba ṣẹ̀, on o kú. Ọmọ kì yio rù aiṣedẽde baba, bẹ̃ni baba kì yio rù aiṣedẽde ọmọ: ododo olododo yio wà lori rẹ̀, ìwa buburu enia buburu yio si wà lori rẹ̀.

Ka pipe ipin Esek 18

Wo Esek 18:20 ni o tọ