Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Esek 17:9 Yorùbá Bibeli (YCE)

Wipe, Bayi ni Oluwa Ọlọrun wi; yio ha gbà? on kì yio hú gbòngbo rẹ̀, kì yio si ka eso rẹ̀ kuro, ki o le rọ? yio rọ ninu gbogbo ewe rirú rẹ̀, ani laisi agbara nla tabi enia pupọ̀ lati fà a tu pẹlu gbòngbo rẹ̀.

Ka pipe ipin Esek 17

Wo Esek 17:9 ni o tọ