Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Esek 17:6 Yorùbá Bibeli (YCE)

O si dagba, o si di igi àjara ti o bò ti o kuru, ẹka ẹniti o tẹ̀ sọdọ rẹ̀, gbòngbo rẹ̀ si wà labẹ rẹ̀; bẹ̃ni o di ajara, o si pa ẹka, o si yọ ọ̀munú jade.

Ka pipe ipin Esek 17

Wo Esek 17:6 ni o tọ